Ìtọ́ka Mùsùlùmí tí a ṣe ní ìrọ̀rùn

Àwọn ìdájọ́ tí a ṣe ní ìrọ̀rùn àti àwọn àlàyé tí ó bá òfin ẹ̀sìn Islām mu, tí ó pàtàkì fún àwọn Mùsùlùmí níbi gbogbo ètò ìgbésí

Ìgbàgbọ́ Mùsùlùmí

Gbogbo iṣẹ́ tí Ọlọ́hun fi rán àwọn Ànábì Rẹ̀ sí àwọn ìjọ wọn papọ̀ lórí jíjọ́sìn fún Ọlọ́hun Allāh nìkan ṣoṣo, kò sí orogún fún Un àti ṣíṣe àìgbàgbọ́ sí ohun tí à ń jọ́sìn fún...

Ìmọ́ra Mùsùlùmí

Ọlọ́hun pa Mùsùlùmí láṣẹ kí ó wẹ inú rẹ̀ àti ọkàn rẹ̀ mọ́ kúrò níbi ẹbọ, àti àwọn àìsàn ọkàn bíi; kèéta, motómotó àti ìlara, àti fífọ ìta rẹ̀ mọ́ kúrò níbi àwọn ẹ̀gbin àti àwọn...

Ìrun Mùsùlùmí

Ìrun ni òpò ẹ̀sìn Islām àti ohun tí ó máa ń da ẹrúsìn Ọlọ́hun mọ́ Ọlọ́hun Ọba rẹ̀ àti Olùgbọ̀wọ́ rẹ̀. Ìdí nìyí tí ó fi jẹ́ pé òhun ni ó tóbi jùlọ nínú àwọn ìjọsìn, òhun ni ipò...

Ààwẹ̀ gbígbà

Ọlọ́hun ṣe ààwẹ̀ gbígbà ní ọ̀ranyàn lórí àwọn Mùsùlùmí fún oṣù kan ṣoṣo nínú ọdún, òhun náà ni oṣù Ramaḍān oníbùkún, Ó sì ṣe é ní orígun kẹrin nínú àwọn orígun ẹ̀sìn Islām àti...

Zakāh yíyọ

Ọlọ́hun ṣe Zakāh yíyọ ní ọ̀ranyàn, Ó sì ṣe é ní orígun kẹta nínú àwọn orígun ẹ̀sìn Islām, Ó sì ṣe ìlérí ìyà tí ó le koko fún ẹni tí ó bá pa á tì, Ó sì so ìjẹ́-ọmọ ìyá papọ̀ mọ́...

Ḥajj ṣíṣe

Ḥajj ṣíṣe lọ sí ìlú Makkah ni orígun karùn-ún nínú àwọn orígun ẹ̀sìn Islām, ó sì jẹ́ ìjọsìn tí ó kó oríṣiríṣi ìjọsìn àfaraṣe, àfọkànṣe àti àfowóṣe sínú. Ṣíṣe é jẹ́ ọ̀ranyàn fún...

Ikú àti òkú sísin

Ikú kì í ṣe òpin ọ̀ràn, ṣùgbọ́n ó jẹ́ ìpele titun fún ènìyàn àti ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀mì tí ó pé ní ọ̀run. Bí ó ti jẹ́ wí pé ẹ̀sìn Islām ṣe ojúkòkòrò ṣíṣe àmójútó àwọn iwọ̀ ènìyàn láti...

Àwọn ìwà Mùsùlùmí

Ìwà, nínú ẹ̀sìn Islām, kì í ṣe àyọ̀pọ̀rá, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe ohun tí ń pé nǹkan, ṣùgbọ́n ó jẹ́ ìpín kan tí ó fi ẹsẹ̀ rinlẹ̀, tí ó so mọ́ ẹ̀sìn ní gbogbo ọ̀nà. Àwọn ìwà, nínú ẹ̀sìn...

Àwọn ìbára ẹni ṣe papọ̀ tí ó ní owó nínú

Ẹ̀sìn Islām gbé gbogbo àwọn ìdájọ́ àti àwọn àgbékalẹ̀ òfin, èyí tí yóò máa mójútó ènìyàn, tí yóò sì máa ṣọ́ àwọn ìwọ̀ rẹ̀ tí ó ní í ṣe pẹ̀lú owó, àti èyí tí ó ní í ṣe pẹ̀lú iṣẹ́-...

Àwọn oúnjẹ

Oúnjẹ tí ó jẹ́ ẹ̀tọ́ ní ipò tí ó tóbi nínú ẹ̀sìn Islām, ó sì jẹ́ okùnfà gbígbà àdúrà àti àlùbáríkà lára owó àti ẹbí. Ohun tí a gbà lérò pẹ̀lú oúnjẹ tí ó jẹ́ ẹ̀tọ́ ni ohun tí ó...

Aṣọ wíwọ̀

Aṣọ wíwọ̀ jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìdẹ̀ra Ọlọ́hun lórí àwọn ènìyàn. Gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́hun, Ọba tí ọlá Rẹ̀ ga, ti wí pé: “Ẹ̀yin ọmọ Ādam! Dájúdájú A ti sọ aṣọ kalẹ̀ fun yín, tí yóò máa bo...

Ẹbí Mùsùlùmí

Ẹ̀sìn Islām ṣe ojú kòkòrò ní gbogbo ọ̀nà láti fi ẹsẹ̀ ẹbí Mùsùlùmí rinlẹ̀ gbọingbọin, àti láti ṣọ́ ọ níbi ohun tí ó le kó ṣùtá bá a, tí ó sì le bi mímọ rẹ̀ wó. Nítorí pé pẹ̀lú...

Àwọn àdúrà àti àwọn ìrántí Ọlọ́hun

Rírántí Ọlọ́hun jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọsìn tí ẹ̀san rẹ̀ tóbi jùlọ, tí ó sì ṣe àǹfààní jùlọ fún ẹrusìn Ọlọ́hun ní ayé àti ní ọ̀run, Mùsùlùmí sì máa ń lékún pẹ̀lú rẹ̀, ní iyì àti...

Láti wo gbogbo àwọn abala Ìtọ́ka Mùsùlùmí tí a ṣe ní ìrọ̀rùn, tẹ ibí yìí

Ọ̀RỌ̀ ÀKỌ́SỌ

Ipò ènìyàn tí ó tóbi jùlọ ni kí ó máa jọ́sìn fún Ọlọ́hun Allāh, kí ó sì máa tẹ̀lé àwọn àṣẹ Rẹ̀. Níbẹ̀ ni dáadáa ayé àti ti ọ̀run wà. Nítorí pé ìrọ̀rún ni gbogbo ohun tí ẹ̀sìn (Islām) mú wá, oore ni gbogbo rẹ̀, dáadáa sì ni gbogbo rẹ̀.                 ...

Ìtọ́ka Mùsùlùmí tí a ṣe ní ìrọ̀rùn

Ààyè Ìtọ́ka Mùsùlùmí tí a ṣe ní ìrọ̀rùn jẹ́ ẹ̀dà orí ẹ̀rọ ayé-lu-jára láti inú ìwé (Ìtọ́ka Mùsùlùmí tí a ṣe ní ìrọ̀rùn). Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn iṣẹ ilé-iṣẹ́ ìtọ́ka ìgbàlódé. A sì ti tẹ̀ ẹ́ jáde pẹ̀lú èdè tó ju 15 lọ. A tún ti mú àkóónú rẹ̀ wá lórí ọlọ́kan-ò-jọ̀kan nínú àwọn ìkànnì ẹ̀rọ ayé-lu-jára tó yanrannti

Modern Guide